client_id stringclasses 6 values | audio audioduration (s) 2.16 10.3 | text stringlengths 21 93 | speaker_id stringclasses 6 values |
|---|---|---|---|
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ọmọ ẹgbẹ́ òkùnkùn dèrò àtìmọ́lé torí nílùú Ìbàdàn. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ìyàwó àwọn ọlọ́pàá tó kú lásìkò ìwọ́de tó kọjá ti bẹ̀bẹ̀ fún ìrànwọ́. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Nítori ọrọ táa sọ lọ́jọ́sí ni Túndé yoo fi kúrò nílé ìwé. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ilẹ̀ mímìtìtì ní ìlú ṣakí ti sọ àwọn olugbé ibẹ̀ sínú hílàhílo. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ìgbòho ní Aláàfin, Ọ̀ọ̀nì, Olúbàdàn tì òun lẹ́yìn. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Àfáà ń wáàsù kí àwọn alátìlẹ́yìn rẹ̀ má gba abẹ́rẹ́ àjẹ́sára. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Awọn gómìnà kankan ti padà sí ẹgbẹ́ òṣèlú onígbàálẹ̀. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ọ̀pọ̀ ènìyàn ló fẹ́ kúrò nílè Nàíjíríà. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ọba ìlú wa kìlọ̀ fún áwọn ọ̀dọ́ lórí ṣíṣe òògùn owó òjijì. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọ̀dọ́ lọ́ fẹ́ fi orílẹ̀ èdè Nàìjíríà sílẹ̀. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Àwọn àjẹ́ ló wà nídí ọ̀rọ̀ Àrẹ̀mú. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Oṣù kan péré ni Àjídé fi ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Adélékè. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Àtisùn ti dogun torí ọ̀rọ̀ àbò ní orílẹ-èdè yìí. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ìwádìí fi hàn pé ikú àrá ló pa àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba mẹ́ta kan. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Àwọn ẹ̀yà Yorùbá máa ń pé ara wọn ní ọmọ ilẹ̀ káàárọ̀-ò-jíire. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ẹgbọ́n mi ni Ọlápọ̀si, ó ní ìyàwó méjì, àti ọmọ mẹ́ta. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ọ̀rẹ́bìnrin méjì ti para wọn torí wọ́n ba ọkọ ara wọn sùn. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ajá mẹ́ta ló ń ṣọ́ ilé ọ̀gá ọlọ́pàá tó wà ní Yemẹtu Ìbàdàn. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ẹ̀sùn bíbá ọmọdé tage kò yẹ àgbàlagbà ọkùnrin. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Àwọn ìlànà yìí yóó ṣe ìrànwọ́ fún àwọn ènìyàn. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ìjà wọn ò ṣeé dá sí kí wọn má baà yi lé èèyàn lórí. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ó jọ bí ẹni pé alága ẹgbẹ́ Iréwọlédé ni Ọlátúndé Adégbuyì. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ṣèyí fojú hàn n'íta fún ìgbà àkọ́kọ́ lẹ́yìn tó ṣẹ́gun ọ̀tá. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ìjọba Ọ̀sun ní abẹ́rẹ́ àjẹsára lọ́wọ́. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Bùnmi tún parọ́ pé òun kọ́ lòun wa ọkọ̀ sáré àsájù. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Gbogbo àwọn ọmọbìnrin ló nílò ìtọ́jú tó dára. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba ti ń kọ́ àwọn èèyàn bí wọ́n ṣe lè dìbò. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Iṣẹ́ àgbẹ̀ ṣe kókó lásìkò yìí. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ǹjẹ́ o mọ̀ nípa Bídèmí tó wọ gàu ní Amẹ́ríkà lórí ẹ̀sùn jì̀bì̀tì̀. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Àwọn adarí ilé iṣẹ́ náà ni ó ń fa wàhálà fún àwọn òṣìṣẹ́ náà. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Kò séwu fún gbogbo àwọn tí yóò kópa nínú ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ ní Èkó. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ìforúkọ sílẹ̀ ti ń lọ lórí ayélujára láti di ọlọ́pàá. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ohun tó ṣẹlẹ̀ níbi àjọ̀dún ẹgbẹ́ wa kọ́wa lọ́gbọ́n gidigidi. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ẹgbẹ́ ọlọ́dẹ pariwo síta lórí ìlànà ìgbanisíṣẹ́ ìjọba. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Mó mu àwọn àlàyé àti ìmọ̀ràn yí ni pàtàkì nínú ìgbésí ayé mi. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Wọ́n sọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ níbi ètò tí mo lọ lọ́jọ́ ìsinmi tó kọjá. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Adìyẹ kan yàgbé sí orí ọkọ̀ mi. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ọlá ń kírun lọ́wọ́ ni wọ́n ta ní ìbọn. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti kó ẹgbẹ̀rún ìrẹsì fún àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Adédoyin ló ni ilé ìtura tó wà lọ́nà Yemẹtu ní Ìbàdàn. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ìpàdé ìdìbò ẹgbẹ́ òṣèlú wa máa wáyé ní ìlú Ìsánlú lọ́túnla. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Àwọn ọlọ́sìn ẹja ní àìríṣẹ́ṣe ló fà gbogbo oun tó ṣẹlẹ̀. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Èèyàn mẹ́rin kú ní Nàíjíríà lónìí. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ta ló fipá bá Fúnkẹ́ lò pọ̀ ní ìlú Ọ̀ṣun? | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Babaláwo Ìgbòho sọ pé àwọn agbófinró ti gbé aṣọ òun lọ. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ìjà wáyé láàrin ọ̀rẹ́ tímọ́-tímọ́ méjì. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Bọ̀sú ti padà yọjú sí àgọ́ ọlọ́pàá lẹ́yìn tí wọ́n ráṣẹ́ pè é. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ó ní kí ìjọba àpapọ̀ náà ṣé àtúnṣe. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Kì í ṣe nǹkan tuntun kí agbábọ́ọ̀lù kú sórí pápá. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ìyáàfin Olúwalóní ti bèèrè fún owó ìtanràn lọ́wọ́ ọlọ́pàá. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ilé-ìwé gíga Èkó ti gba Bùsáyọ̀ wọlé. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Àwọn mẹ́fà kú nínú àwọn sójà tí ó lọ jà fún ìlú. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ewu wo làwọn òṣìṣẹ́ elétò ìlèra ń kojú ní Nàìjíríà? | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ikú ààrẹ̀ ìjọ́sí jẹ́ oun tó dun gbogbo ìlú gidigidi. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Bọ́lá fẹ́ ja mí lólè, ṣùgbọ́n Ọlọ́run kò gbà fún-un. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Bàbá mi kọ̀ láti bá mi sọ̀rọ̀ torí ọ̀kọ akáta tí mo mú wálé. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Wọ́n gbà pé owó ni àwọn ará Èkó ń lé, wọn kò ní Ọlọ́run. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Àwọn ọ̀dọ́ ìlú Ọ̀ffa fàákékọ́rí lórí ìwọ́de náà. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Àwọn olórin tún máa ń mọ ìtàn nípa èèyàn, ìdílé àti ìlú lápapọ̀. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ẹyọ kan ṣoṣo ló wá láti tọ̀jú aláìsàn nínú àwọn òṣìṣẹ́ náà. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ìjọba ìpínlẹ̀ Ògùn ti gbé ìlànà mìíràn láti fi ṣe ìsìnkú ọba. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ọ̀dọ̀ fásitì kan ní ìlú Èkó ló ṣe òògùn ìtura yìí. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ọlọ̀pàá yin àwọn aráàlú tí wọ́n kígbe síta. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Nkò le ṣeré pẹ̀lú ọkùnrin tí mi ò mọ rí lẹ́yìn ìgbeyàwó mi. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ọkọ ọbabìnrin ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sí àti àwọn ọmọ rẹ̀ ni wọ́n pé jọ. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Báwo ni àwọn ikọ̀ yìí yóó ṣe dáná sun ara wọn? | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Wọ́n má ń fipá bá obìnrin kan lòpò láàárín wákàtí mẹ́ta. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ọmọ tó bí sọ́gbà ẹ̀wọ̀n ló kọ̀kọ́ gba ẹ̀bùn ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Àwọn ọmọ náà jẹ àgbàdo lójú títì. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ẹni tó dábàá èlé owó epo ti tún bá ìjọba já nítorí àríyànjiyàn. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ìgbà tí wọ́n dé Ìbàdàn, wọ́n kọ́ ilé sí agbègbè Mọ̀lété. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Iṣẹ́ ti bẹ̀rẹ̀ ní pẹrẹu fún Àmọ̀tẹ́kùn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ọ̀lọ́pàá sọ pé ìjọba àpapọ̀ kò ran àwọn lọ́wọ́ tó bó ṣe yẹ. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Alágbádá ti gbóṣùbà fún Gbóyèga Fámọdún kó tó gbée lọ sílé ẹjọ́. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Tàlàbí ní ìwọ́de kọ́ ni Ààrẹ ọ̀nà Kakańfò fi ń bẹ̀rẹ̀ ogun. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ilé aṣòfin ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti wó. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Àwọn Adigunjàlè kọlu ilé-ìfowópamọ́ ní Ọṣun. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ṣèyí Mákindé ti yọ àwọn olùkọ́ kúrò nípò. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Mo ti gbà fún Ọlọ́run níbi tí mo wà báyìí ni Ìgbòho sọ. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Àwọn jàndùkú jí agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà méjì gbé lópòpónà. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ìjọba àpapọ̀ ti ra abẹ́rẹ́ àjẹsára onígbá méjì ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ìyà ló ń jẹ àwọn nọ́ọ̀sì ní Ọ̀wọ̀ tí wọ́n fi ń bínú. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ẹni ṣiṣẹ́ jàre ìṣẹ́ ni àwọn Yorùbá máa ń wí. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Àwọn àwòrán tí wọ́n yà níbi ìgbéyàwó ọmọ ààrẹ kò dára. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Jọ̀wọ́ bá mi kí ìyá wa pẹ̀lú ọmọ pupa mi, Oyindàmọ́lá. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ó ṣe pàtàkì fún gbogbo ọmọ ìlú lái dìbò yan aṣojú wọn. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ọkùnrin méjì ló fi mágùn sí orí ìyàwó rẹ̀ ní Bashọ̀run. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ẹlòmíìran ń fi irú ọyàn wa tọrọ. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Àjọ aṣọ́nà kìlọ̀ f'áwọn awakọ̀ tó máa tẹ fóònù lórí ìrin ní Èkó. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Gómìnà Bùkọ́lá fún Dókítà ní àmì ẹ̀yẹ fún ìṣẹ́ takuntakun. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ìdájọ́ òdodo nìkan ni mò ń bèèrè fún lórí ọ̀rọ̀ Bàbá Ìjẹ̀ṣà. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Kò sí ààyè láti fẹ́ran Akérédolú ju Arígbábuwó lọ. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ọ̀rẹ́ bí ọmọ ìyá ni èmi àti Ìfẹ́dọ̀lápọ̀, alábáárò mi ni ó ń ṣe. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Ọmọ ọdún mẹ́tàdínláàdọ́ta kan ló pa ọkọ ẹ̀ nítorí owó. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Tọ́lá tún wá sí ààfin láìmú ọkọ wá. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | O ti tó àádọ́ta ọdún tí a ti fi ẹ̀sùn kan Ìgbòho àti Káyọ̀dé. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Àwọn agbénipa tí wọ́n jí ọmọ náà gbé ní ojú pópó lásán ló paá. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Àlékún bá iye owó búrẹ́dì ní ìlú Èrúwà. | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Kí gan-an láwọn nǹkan tó n fa àìsàn ibà ní àgọ̀-ara? | 7bc2ed85985f28a | |
7bc2ed85985f28af0f62be69494e94d712557f6d7893a0af9683a576d4e0e57dfe78d249b6f51ee6efd98c69f96c053ef723b075b391625f683a2153cb5184c7 | Dọ́kítà kan ti sọ àwọn ìdí tí obìnrin fi dára ju ọkùnrin lọ. | 7bc2ed85985f28a |
End of preview. Expand
in Data Studio
No dataset card yet
- Downloads last month
- 12